1 Ọlọ́run sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí pé,
18 Nígbà tí àwọn ènìyàn náà rí mọ̀nàmọ́ná tí wọ́n sí gbọ́ ohùn ìpè àti èéfín tí ń rú láti orí òkè, tí wọ́n sì gbọ́ sísán àrá, dídún ìpè kíkankíkan; wọ́n dúró ní òkèrè wọ́n sì ń gbọ̀n ṣìgàṣìgà fún ìbẹ̀rù. 19 Wọ́n wí fún Mose pé, “Ìwọ fúnra rẹ̀ máa bá wa sọ̀rọ̀, àwa yóò sì gbọ́. Má ṣe jẹ́ kí Ọlọ́run fúnra rẹ̀ kí ó bá wa sọ̀rọ̀, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, àwa yóò kú.”
20 Mose sì sọ fún àwọn ènìyàn náà pé, “Ẹ má bẹ̀rù. Ọlọ́run wá láti dán an yín wò, kí ẹ̀rù Ọlọ́run kí ó lè máa wà ní ara yín, kí ẹ̀yin kí ó má ṣe ṣẹ̀.”
21 Àwọn ènìyàn sì dúró ní òkèèrè nígbà tí Mose súnmọ́ ibi òkùnkùn biribiri níbi tí Ọlọ́run wà.
22
24 [~16~]“ ‘Pẹpẹ erùpẹ̀ ni kí ìwọ mọ fún mi. Ní orí pẹpẹ yìí ni kí ìwọ ti máa rú ẹbọ sísun rẹ sí mi àti ẹbọ àlàáfíà rẹ, àgùntàn rẹ, ewúrẹ́ àti akọ màlúù rẹ. Ní ibi gbogbo tí mo gbé fi ìrántí orúkọ mi sí, èmi yóò sì máa tọ̀ ọ́ wá, èmi yóò sì máa bùkún ọ níbẹ̀. 25 [~17~]Bí ìwọ bá ṣe pẹpẹ òkúta fún mi, má ṣe fi òkúta tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ kọ́ ọ, nítorí bí ìwọ bá lo ohun ọnà rẹ lórí rẹ̀, ìwọ sọ ọ di àìmọ́. 26 Ìwọ kò gbọdọ̀ gun àkàsọ̀ lọ sí ibi pẹpẹ mi, kí àwọn ènìyàn má ba à máa wo ìhòhò rẹ láti abẹ́ aṣọ tí ìwọ wọ̀ nígbà tí ìwọ bá ń gòkè lọ sí ibi pẹpẹ.’
<- Eksodu 19Eksodu 21 ->20:2 De 5.6-21.
20:3 Ek 20.23; De 5.7.
20:4 Ek 20.23; 34.17; Le 19.4; 26.1; De 4.15-19; 5.8; 27.15.
20:5 Ek 23.24; 34.6,7,14; De 4.24; 5.9,10; 7.9.
20:7 Le 19.12; De 5.11.
20:8 Ek 23.12; 31.12-17; 34.21; 35.2,3; Le 19.3; De 5.12-15.
20:12 Mt 19.18,19; Mk 10.19; Lk 18.20.
20:12 Le 19.3; De 5.16; Mt 15.4; Mk 7.10; Ef 6.2.
20:13 Gẹ 9.6; Ek 21.12; Le 24.17; De 5.17; Mt 5.21; Jk 2.11.
20:13 Ro 13.9.
20:14 Le 20.10; De 5.18; Mt 5.27; Ro 7.7.
20:15 Le 19.11; De 5.19.
20:16 Ek 23.1; De 5.20.
20:17 De 5.21; Ro 7.7.
20:23 Ek 20.3,4; 34.17; De 27.15.
20:24 Ek 27.1-8; De 12.5; 26.2.
20:25 De 27.5-7; Jo 8.31.